Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Nígbà yẹn, ìjọ ló máa ń dìbò yan àwọn alàgbà sípò. Torí náà, ìjọ kan lè kọ̀ láti dìbò fún àwọn ọkùnrin tó bá ta ko iṣẹ́ ìwàásù. A ó sọ̀rọ̀ nípa bí a ṣe bẹ̀rẹ̀ sí í yan àwọn alàgbà lọ́nà ti ìṣàkóso Ọlọ́run ní Orí 12.