Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì nígbà yẹn ti lóye òtítọ́ pàtàkì yìí. Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ lédè Gẹ̀ẹ́sì ti November 15, ọdún 1895, sọ pé: “Bó bá tiẹ̀ jẹ́ àlìkámà díẹ̀ lá rí kó jọ, ó kéré tán à ń jẹ́rìí ní kíkún sí òtítọ́. . . . Gbogbo èèyàn ló lè wàásù ìhìn rere.”