Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Àwọn èèyàn Jèhófà tó wà lórí ilẹ̀ ayé ń jọ́sìn rẹ̀ nínú àwọn àgbàlá orí ilẹ̀ ayé ti tẹ́ńpìlì ńlá tẹ̀mí.