Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ẹ̀jẹ́ náà ò fàyè gba kí ọkùnrin kan àti obìnrin kan jọ wà pa pọ̀ nínú yàrà kan náà, àyàfi tí wọ́n bá ṣí ilẹ̀kùn sílẹ̀ gbayawu tàbí tí wọ́n bá jẹ́ tọkọtaya tàbí ìbátan tímọ́tímọ́. Fún ọdún bíi mélòó kan, wọ́n máa ń ka ẹ̀jẹ́ yìí lójoojúmọ́ ní Bẹ́tẹ́lì nígbà Ìjọsìn Òwúrọ̀.