Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ọ̀mọ̀wé kan sọ pé ọ̀rọ̀ Gíríìkì tá a túmọ̀ sí “pinnu” “ní í ṣe pẹ̀lú ohun téèyàn ti gbèrò tẹ́lẹ̀ láti ṣe.” Ó wá fi kún un pé: “Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ayọ̀ máa ń wà nínú fífúnni, síbẹ̀ ó gba pé kéèyàn ti wéwèé irú nǹkan bẹ́ẹ̀ sílẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ.”—1 Kọ́r. 16:2.