Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tẹ́ńpìlì tẹ̀mí ni ètò tí Jèhófà ṣe ká lè máa jọ́sìn rẹ̀ lọ́nà tó tọ́ lọ́lá ẹbọ ìràpadà Jésù Kristi. A lóye pé ètò yìí bẹ̀rẹ̀ lọ́dún 29 Sànmánì Kristẹni