Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ìran tẹ́ńpìlì tí Ìsíkíẹ́lì rí tún bá àwọn àsọtẹ́lẹ̀ míì tó nímùúṣẹ lọ́jọ́ ìkẹyìn mu nípa bí nǹkan ṣe pa dà bọ̀ sípò. Bí àpẹẹrẹ, wo bí Ìsíkíẹ́lì 43:1-9 àti Málákì 3:1-5 ṣe jọra; bákan náà, wo bí Ìsíkíẹ́lì 47:1-12 àti Jóẹ́lì 3:18 ṣe jọra.