Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tí ọtí àmujù bá ti di bárakú fún ẹnì kan, ohun tó máa dáa ni pé kó lọ rí àwọn dókítà tó máa ń tọ́jú àwọn tí ọtí ti di bárakú fún. Ohun tí ọ̀pọ̀ àwọn dókítà sọ ni pé tẹ́nì kan bá ti níṣòro ọtí mímu rí, kò yẹ kónítọ̀hún tún fẹnu kan ọtí mọ́ rárá.