Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Diẹ ninu awọn kika rẹ̀ ti o tubọ ṣe pataki ni a tọkasi ninu New World Translation of the Holy Scriptures—With References ni Aisaya 11:1; 12:2; 14:4; 15:2; 18:2; 30:19; 37:20, 28; 40:6; 48:19; 51:19; 56:5; 60:21. Iwe akajọ naa ni a fihan yatọ ninu alaye eti iwe gẹgẹ bi 1QIsa.