Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọjọgbọn Paul Haupt ṣalaye pe: ‘Ninu àkójọ awọn ohun ìṣẹ̀m̀báyé ti sanmani agbedemeji awọn ìwo ẹranko bii àgbáǹréré tabi ehin gigun ti ẹran omi narwhal (ti a tun ń pè ni ẹja unicorn tabi ẹja àbùùbùtán ti unicorn) ni a kàsí awọn ìwo unicorn.’