Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bíbọ́ lọwọ ìwà imukumu ọtí jẹ́ iṣẹ́-òpò kan ti o ṣòroó bori, ti o ń bere fun iranlọwọ olóye iṣẹ niye ìgbà. Wo iwe irohin alabaakẹgbẹ wa, Ji! ti May 22, 1992 (Gẹẹsi), fun isọfunni ti ó lè ṣeranlọwọ lori kókó ẹ̀kọ́ yii.