Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nigba ti Luku 3:23 sọ pe: “Josefu, tíí ṣe ọmọ Eli,” ó ṣe kedere pe ó tumọsi “ọmọ” ni èrò itumọ ti “ọkọ-ọmọbinrin,” niwọn bi Eli ti jẹ́ baba Maria nipa ti ara.—Insight on the Scriptures, Idipọ 1, oju-iwe 913 si 917.