Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Josephus opitan Ju, nigba ti ó ń gbe ìlà-ìran tirẹ kalẹ, mú un ṣe kedere pe iru awọn akọsilẹ bẹẹ wà larọọwọto ṣaaju 70 C.E. Awọn akọsilẹ wọnyi ni ó hàn gbangba pe a parun pẹlu ilu Jerusalemu, ní mímú gbogbo ìjẹ́wọ́ ipo Messia lẹhin naa jẹ́ eyi ti kò ṣeé fẹ̀rí rẹ̀ hàn.