Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a “‘Àgbèrè’ ní ọ̀nà gbigbooro, ati gẹgẹ bi a ṣe lò ó ninu Matteu 5:32 ati 19:9, tọka dajudaju si ìlò gbigbooro ti ibalopọ takọtabo alaibofinmu tabi alaitẹlelana lẹhin ode igbeyawo. Porneia [ọ̀rọ̀ Griki naa ti a lò ninu awọn ẹsẹ-iwe mimọ wọnni] ní ninu ìlò (awọn) ẹ̀yà-ara ibimọ lọna aimọ ti o gadabú, ó kere tán ti eniyan kanṣoṣo (yala ni ọ̀nà ti ẹ̀dá tabi ni ọ̀nà òdì); pẹlupẹlu, ẹlomiran kan ti gbọdọ wà bi alajọpin iwa aimọ naa—eniyan kan yala ọkunrin tabi obinrin, tabi ẹranko kan.” (Ilé-Ìṣọ́nà, September 15, 1983, oju-iwe 30) Panṣaga: “Ibalopọ takọtabo ti a fínnú-fíndọ̀ ṣe laaarin ẹnikan ti ó ti gbeyawo ati ẹnikeji ti kìí ṣe ọkọ tabi aya ti ó bofinmu.”—The American Heritage Dictionary of the English Language.