Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Orilẹ-ede Israeli ni ó hàn kedere pe ó lékè ninu iṣẹ orin. Aworan gbígbẹ́ awọn ara Assiria kan ṣí i payá pe Ọba Sennakeribu beere fun awọn olorin ọmọ Israeli gẹgẹ bi owó-òde lati ọ̀dọ̀ Ọba Hesekiah. Grove’s Dictionary of Music and Musicians ṣakiyesi pe: “Lati beere fun awọn akọrin gẹgẹ bi owó-òde . . . jẹ ohun ti o ṣara-ọtọ niti gidi.”