Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé àlàyé-ọ̀rọ̀ Bibeli Herders Bibelkommentar, nígbà tí ó ń ṣàlàyé Orin Dafidi 103:14, sọ pé: “Ó mọ̀ dájú pé oun dá ẹ̀dá ènìyàn lati inú erùpẹ̀ ilẹ̀, ó sì mọ awọn àìlera ati ìgbésí-ayé aláìdúrópẹ́ wọn lọ́nà ti ẹ̀dá, èyí tí ó ti ní ipa-ìdarí lílágbára lórí wọn lati ìgbà ẹ̀ṣẹ̀ ìpilẹ̀ṣẹ̀.”—Ìkọ̀wé wínníwínní jẹ́ tiwa.