Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn ohun èèlò tí a gé láti inú ìgbẹ́ tàbí igbó ẹgàn ni a fi ń kọ́ ilé ewé. Igi àti òpó ni a fi ṣe férémù, òrùlé àti ara ògiri ní a sì bò pẹ̀lú ohun èèlò tí a fi ń bo ògiri tí a fi imọ̀-ọ̀pẹ ṣe tí a sì fi ìtàkùn hun papọ̀ mọ́ ara igi.