Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Gẹ́gẹ́ bí ọ̀mọ̀wé akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ nínú Bibeli R. C. H. Lenski ti sọ, “ohùn tí” Pilatu “fi sọ̀rọ̀ jọ ti ẹni ayé kan tí ń fi ọ̀rọ̀ dágunlá tí ó sì tipa ìbéèrè rẹ̀ ní in lọ́kàn láti sọ pé ohunkóhun tí ó bá jẹmọ́ ti òtítọ́ ìsìn jẹ́ ìméfò tí kò níláárí.”