Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Ọ̀rọ̀ Griki náà fún “òtítọ́,” a·leʹthei·a, ni a fàyọ láti inú ọ̀rọ̀ kan tí ó túmọ̀ sí “ohun tí a kò fi pamọ́,” nítorí náà òtítọ́ máa ń wémọ́ ṣíṣí ohun tí ó wà ní ìkọ̀kọ̀ tẹ́lẹ̀ payá.—Fiwé Luku 12:2.