Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
e Ìwé Àfọwọ́kọ Alábala Cairo (895 C.E.), tí ó ní kìkì àwọn wòlíì ti ìṣáájú àti ti ìgbẹ̀yìn nínú, fúnni ní àpẹẹrẹ ọ̀nà ti Moses. Àwọn ìwé àfọwọ́kọ alábala ti Aleppo (c.930 C.E.) àti Leningrad (1008 C.E.) ni a mọ̀ sí àpẹẹrẹ àwọn ọ̀nà ti Aaron Ben Asher.