Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ọ̀rọ̀ náà tí a pè ní “àwọn onídàájọ́” nínú Danieli 7:10, 26 ni a tún rí nínú Esra 7:26 àti Danieli 4:37; 7:22.