Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Fún àpẹẹrẹ, àwọn kan lè jìjàkadì láti ṣàkóso àkópọ̀ ìwà kan tí ó ti wọ̀ wọ́n lẹ́wù, irú bí inú fùfù, tàbí láti borí ìṣòro ìdánìkan hùwà ìbálòpọ̀.—Wo Jí!, November 22, 1988, ojú ìwé 19 sí 21; May 8, 1983, ojú ìwé 13 sí 19; àti Awọn Ìbéèrè Tí Awọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Awọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, ojú ìwé 198 sí 211, tí a tẹ̀ jáde láti ọwọ́ Watchtower Bible and Tract Society of New York, Inc.