Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a A ṣàkọsílẹ̀ pé, ìdì èso àjàrà kan láti ẹkùn ilẹ̀ yìí wọn kìlógírámù 12, òmíràn sì wọ̀n ju 20 kìlógírámù.