Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Irú àwọn ilé bẹ́ẹ̀ kò dà bí ilé àwọn ọkùnrin ajẹ́jẹ̀ẹ́ anìkàndágbé ti Kirisẹ́ńdọ̀mù. Kò sí àwọn “olórí ilé àwọn ọkùnrin ajẹ́jẹ̀ẹ́ ìsìn,” tàbí “àwọn bàbá,” ní èrò ìtumọ̀ ìyẹn níbẹ̀. (Mátíù 23:9) A ń bọ̀wọ̀ fún àwọn arákùnrin tí wọ́n ṣeé fa ẹrù iṣẹ́ lé lọ́wọ́, ṣùgbọ́n ìlànà kan náà tí ń darí àwọn alàgbà ní ń darí iṣẹ́ ìsìn wọn.