Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Lára àwọn ìlú tí ó ṣe pàtàkì jù lọ ní Makedóníà, Fílípì ní ìfiwéra, jẹ́ ìpínlẹ̀ ọlọ́rọ̀, tí ó jẹ́ ti ológun, tí jus italicum (Òfin Ítálì) ń ṣàkóso. Òfin yìí fún àwọn ará Fílípì lẹ́tọ̀ọ́ tí ó jọ ti èyí tí àwọn ará Róòmù ń gbádùn.—Ìṣe 16:9, 12, 21.