Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ó dùn mọ́ni pé, ọ̀rọ̀ Hébérù náà tí a tú sí “ẹ̀dá wa” ni a lò fún ohun èlò àfamọ̀ṣe tí amọ̀kòkò mọ.—Aísáyà 29:16.