Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Títú u sí “ìyá ìyá rẹ̀” ní 2 Tímótì 1:5 ní èdè Síríákì fi hàn pé Lọ́ìsì kì í ṣe ìyá bàbá Tímótì.