Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ní àwọn àdúgbò kan, ọ̀ràn kò rí bẹ́ẹ̀. Àwọn òbí ọkọ ló máa ń retí àtigbà nǹkan ìdána lọ́wọ́ àwọn òbí ìyàwó.