Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bí The New English Bible ṣe tú Sáàmù ìkẹrìndínlọ́gọ́rùn-ún, ẹsẹ ìkíní ni pé: “Ẹ kọrin sí OLÚWA, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn ilẹ̀ ayé.” The Contemporary English Version kà pé: “Gbogbo ẹni tó wà lórí ilẹ̀ ayé yìí, ẹ kọrin ìyìn sí OLÚWA.” Èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú òye náà pé “ilẹ̀ ayé tuntun” tí Aísáyà ń tọ́ka sí ni àwọn ènìyàn Ọlọ́run tí wọ́n wà ní orílẹ̀-èdè wọn.