Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Élíásárì àti Ítámárì, ìyẹn àwọn ọmọ Áárónì méjì yòókù jẹ́ àwòkọ́ṣe nínú iṣẹ́ ìsìn wọn sí Jèhófà.—Léfítíkù 10:6.