Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Tó o bá fẹ́ mọ orúkọ àwọn ọba Júdà bí wọ́n ṣe jẹ tẹ̀ lé ara wọn, wo Ilé Ìṣọ́, August 1, 2005, ojú ìwé 12.