Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó yẹ kí tọkọtaya máa dárí ji ara wọn kí wọ́n sì yanjú ìṣòro tí wọ́n bá ní, Bíbélì fàyè gbà á kí ẹnì kan pinnu yálà láti dárí ji ọkọ tàbí aya tó ṣe panṣágà tàbí kó kọ̀ ọ́ sílẹ̀. (Mát. 19:9) Wo àpilẹ̀kọ náà, “Ojú-Ìwòye Bibeli: Panṣágà—Ṣé Kí N Dáríjì Í Tàbí Kí Ń Máṣe Dáríjì Í?” nínú Jí! August 8, 1995.