Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tó o bá fẹ́ mọ ohun tó o lè ṣe tó bá ń ṣe ẹ́ bíi pé kó o pa ara ẹ, wo àwọn àpilẹ̀kọ tó wà nínú àwọn Jí! tá a mẹ́nu kàn yìí: “Má Ṣe Jẹ́ Káyé Sú Ẹ Ìdí Mẹ́ta Tó Fi Yẹ Kó O Ṣì Wà Láàyè” (May 2014); “Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé Kó O Gbẹ̀mí Ara Rẹ” (April 2012); àti “Ìrànwọ́ fún Àwọn Obìnrin Tí Ọkọ Wọn Ń Lù” (November 8, 2001) ojú ìwé 13 sí 22.