Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Tí àwọn tá a ti yọ lẹ́gbẹ́ àtàwọn tó mú ara wọn kúrò lẹ́gbẹ́ bá wá sípàdé, ká má gbàgbé ìlànà Bíbélì tó sọ pé ká fi ààlà sí àjọṣe wa pẹ̀lú irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀.—1Kọ 5:11; 2Jo 10.