Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn akéde tó ti ṣèrìbọmi lè gba káàdì DPA fún ara wọn, wọ́n sì lè gba káàdì ìdánimọ̀ fún àwọn ọmọ wọn kéékèèké.