Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀWÒRÁN: Àwòrán yìí jẹ́ ká rí bí àwọn bàbá kan ṣe ń tọ́jú àwọn ọmọ wọn: bàbá kan ń tẹ́tí sí ọmọ rẹ̀, bàbá kan pèsè ohun tí ọmọbìnrin rẹ̀ máa jẹ, bàbá kan ń dá ọmọ rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́, bàbá kan sì ń tu ọmọ rẹ̀ nínú. Àwòrán ọwọ́ Jèhófà tó wà lẹ́yìn wọn jẹ́ ká mọ bí Jèhófà ṣe ń pèsè fún wa ní gbogbo ọ̀nà.