Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A mọ̀ pé Jèhófà Baba wa nífẹ̀ẹ́ wa gan-an, ó sì mú ká di ara ìdílé rẹ̀. Ìdí nìyẹn táwa náà fi nífẹ̀ẹ́ rẹ̀. Àmọ́ báwo la ṣe lè fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ rẹ̀? Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí àwọn ohun pàtó tá a lè ṣe láti fi hàn bẹ́ẹ̀.