Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọ àwọn ìlànà táá jẹ́ ká mọ ìgbà tó yẹ ká sọ̀rọ̀ àti ìgbà tó yẹ ká dákẹ́. Tá a bá fi àwọn ìlànà yìí sọ́kàn, tá a sì ń fi wọ́n sílò, ọ̀rọ̀ wa máa múnú Jèhófà dùn.