Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀWÒRÁN: (1) A lè kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìgbésí ayé Jésù àti iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ nígbà Ìjọsìn Ìdílé wa. (2) Nínú ìjọ, ó yẹ ká ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe ká lè wà ní àlàáfíà pẹ̀lú àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa. (3) Tá a bá ń lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ ìwàásù nígbà gbogbo, àwọn arákùnrin Kristi là ń tì lẹ́yìn. (4) Tí wọ́n bá da ìjọ wa pọ̀ pẹ̀lú ìjọ míì, ẹ jẹ́ ká fọwọ́ sowọ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn alàgbà.