Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d ÀWÒRÁN: Nígbà ìjọsìn ìdílé, àwọn òbí kan ṣàlàyé àwọn àsọtẹ́lẹ̀ nípa ìpọ́njú ńlá fún àwọn ọmọ wọn.