Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A máa jíròrò àpẹẹrẹ àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù nínú àpilẹ̀kọ yìí. A máa rí i pé tá a bá lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀, Jèhófà máa fún wa lágbára ká lè fara da inúnibíni àti ìwọ̀sí ká sì lè borí àwọn kùdìẹ̀-kudiẹ tàbí àìlera wa.