Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Onírúurú nǹkan ló lè mú ká di aláìlera, ó lè jẹ́ torí àìpé wa, torí pé a ò lówó lọ́wọ́, torí pé à ń ṣàìsàn tàbí torí pé a ò fi bẹ́ẹ̀ kàwé. Yàtọ̀ síyẹn, àwọn alátakò máa ń bú wa tàbí kí wọ́n tiẹ̀ bá wa jà.