Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
f ÀWÒRÁN: Gbogbo ìgbà ni arábìnrin kan tó wà nílé ìwé máa ń rí ohun tí wọ́n fi ń gbé ìbẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀ lárugẹ. (Láwọn ilẹ̀ kan, àmì tó ní oríṣiríṣi àwọ̀ ni wọ́n máa ń fi polówó àwọn abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀.) Nígbà tó yá, arábìnrin náà ṣèwádìí kí ohun tó gbà gbọ́ lè túbọ̀ dá a lójú. Ìyẹn sì mú kó lè gbèjà ìgbàgbọ́ ẹ̀.