Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀWÒRÁN: Ọkùnrin kan tó jẹ́ Amerindian tó ti kú lọ́pọ̀ ọgọ́rùn-ún ọdún sẹ́yìn jíǹde nígbà Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso Kristi. Arákùnrin kan tó la Amágẹ́dọ́nì já ń kọ́ ọkùnrin náà lẹ́kọ̀ọ́ kó lè mọ ohun tó máa ṣe láti jàǹfààní nínú ẹbọ ìràpadà Kristi.