Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀWÒRÁN: Arákùnrin kan tó jẹ́ ọ̀dọ́ ń sọ fún arákùnrin míì tó dàgbà jù ú lọ nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ sí i nígbà tó ṣe ìpinnu tí kò tọ́. Arákùnrin náà (lápá ọ̀tún) fara balẹ̀ tẹ́tí sí i kó lè mọ̀ bóyá kóun gbà á nímọ̀ràn tàbí kóun má ṣe bẹ́ẹ̀.