Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d ÀWÒRÁN: (2) Nígbà tó gba ìsinmi ọ̀sán níbi iṣẹ́, ó ka Bíbélì Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run kó lè mọ ohun tí Jèhófà fẹ́ kóun ṣe.