Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé h ÀWÒRÁN: (6) Ó ń mú kí ìrètí tó ní túbọ̀ dá a lójú bó ṣe ń ronú nípa ọjọ́ iwájú aláyọ̀ tá à ń retí.