Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jèhófà kì í fi wá wé àwọn míì. Àmọ́, nígbà míì àwọn kan lára wa máa ń fi ara wọn wé àwọn míì, ìyẹn sì máa ń jẹ́ kí wọ́n ro ara wọn pin. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ìdí tí kò fi yẹ ká máa ṣe bẹ́ẹ̀. A tún máa rí bá a ṣe lè mú káwọn tá a jọ wà nínú ìdílé àtàwọn míì nínú ìjọ máa wo ara wọn bí Jèhófà ṣe ń wò wọ́n.