Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Láìka ibi tá a ti wá sí, gbogbo wa la lè fi “ìwà tuntun” wọ ara wa láṣọ. Ká tó lè ṣe bẹ́ẹ̀, a gbọ́dọ̀ yí ọ̀nà tá à ń gbà ronú pa dà, ká sì fìwà jọ Jésù. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa bí Jésù ṣe ń ronú àti bó ṣe ń ṣe nǹkan. A tún máa sọ̀rọ̀ nípa bá a ṣe lè máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù lẹ́yìn tá a bá ti ṣèrìbọmi.