Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ká lè lóye ọ̀rọ̀ yìí dáadáa, a máa pe ẹni tó ṣàgbèrè ní ọkùnrin, àá sì pe ẹni tí kò ṣàgbèrè ní obìnrin. Àmọ́ ìmọ̀ràn tí Jésù fún wa lórí ọ̀rọ̀ yìí ní Máàkù 10:11, 12 jẹ́ ká mọ̀ pé bí ọ̀rọ̀ náà ṣe kan ọkùnrin, bẹ́ẹ̀ náà ló kan obìnrin.